About Resouces

OHUN TÍ Ó YE KÍ O MÒ NÍPA ÈDÈ YORÙBÁ

OHUN TÍ Ó YE KÍ O MÒ NÍPA ÈDÈ YORÙBÁ

Resource Code: 4758922

ÌTUMÒ ÀWON ÒRÒ TÍ A KÒ LÒ MÓ NÍNÚ
ÈDÈ YORÙBÁ
I. ISUN : O tumo si obinrin.
ii. IWALE : O tumo si okunrin
III. EJA N BAKAN : o dara tabi ko dara .
iv. OLOGUNNAKAN SOSO : Eni ti o bi omo Kan soso iba je okunrin tabi obinrin.
V. AAYO :iyawo ti oko feran ju.
Vi. AREMO: Akobi omoba lokunrin.
Vii. OPO : Obinrin ti oko re ti ku.
Viii. IDI IGI : Iya àti àwon omo re.
IX. DAODU :Akobi omokunrin Nile Yoruba .
X. BEERE: Akobi omobinrin Nile Yoruba.
Xi. IYEKAN: Àwon omo ti a bi nipase iya àti baba kannaa.
Xii. OBAKAN: Àwon omo ti a bi nipase iya kannaa sugbon otoooto Ni baba won.
Xiii. APON : Omokunrin tabi omobinrin to ti balaga sugbon ti ko tii loko tabi laya.
XIV. IPEERE: Àwon omo to sese n mura à ti di odo.
XV. DALEMOSU: Obinrin to ti ko oko re sile , o wa lo n gbe ile baba re.
XVI. OMO OSU : Obinrin to kuro nile oko re lati lo gbe ile baba re fun idi Kan tabi ekeji . Bi o ba ti pari ohun ti o lo se Nile baba re o leto a ti pada sile oko re. Amo oun o ko oko re sile. O le je o lo fun inawo tabi apero pataki Nile baba re.
XVII. MAJESIN: omo kekere ti ko o tii Fi bee mo owo otun yato si ti osi.
XVIII. ODO : Omokunrin tabi omobinrin to ti balaga.
XIX . Omidan : Omobinrin to ti balaga sugbon ti ko tii loko.
XX. OLORI: Iyawo oba/ kabiesi.

Resource Material: IMG_202007200_142030677.jpg (jpg)