About Resouces

AFRICAN POETRY ( ÈWÌ YORÙBÁ)

AFRICAN POETRY ( ÈWÌ YORÙBÁ)

Resource Code: 9568688

MÁJÈMÚ ( convenant)
Adehun farape MÁJÈMÚ
MÁJÈMÚ farape adehun
Ibi a jo foro ti si lo n je Adehun
Ma ye adehun lodi MÁJÈMÚ
Agbara to nipon lo n be ninu MÁJÈMÚ
Ifenukonu di MÁJÈMÚ laaarin lokolaya
Oruka igbeyawo nko ? Ara MÁJÈMÚ Ni
Ore meji e ranti MÁJÈMÚ te e da
Ohun to Ni I se logun odun ma wule damoran re Lodun ta a wa yiii
Eni da MÁJÈMÚ ti o muse o ti jogun lowo
Lakaaye ti ro n ti o Fi Sata
Eyin te se ileri te e muse , MÁJÈMÚ le da laimo
ko pon dandan keje o Tara MÁJÈMÚ Jade
Adehun ladehun nje mo wi to.
ohun to ba ti lagbara a ti se dakun sewe a gbeje mowo, a kii Muni si.
tori Ai madehun se ewu nla Ni.
Kosi ibi ti o le jasi fun ni.

Resource Material: IMG_20201112_095917~2.jpg (jpg)